1 Chronicles 4:43 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n pa àwọn ọmọ Amaleki yòókù tí wọ́n sá àsálà, wọ́n sì ń gbé orí ilẹ̀ wọn títí di òní olónìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si kọlù iyokù awọn ara Amaleki, ti nwọn salà, nwọn si ngbe ibẹ titi di oni yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì pa àwọn ará Ámálékì tí ó kù àwọn tí ó ti sá lọ, wọ́n sì ti ń gbé bẹ̀ láti òní yìí.