1 Chronicles 5:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ẹ̀yà Gadi ń gbé òdìkejì ẹ̀yà Reubẹni ní ilẹ̀ Baṣani, títí dé Saleka:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Gadi ngbe ọkánkan wọn, ni ilẹ Baṣani titi de Salka:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn ọmọ Gádì ń gbé ọ̀kánkán wọn, ní ilẹ̀ Básánì títí dé Sálíkà: