1 Chronicles 5:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n gbógun ti àwọn ará Hagiriti, Jeturi, Nafiṣi ati Nodabu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si ba awọn ọmọ Hagari jagun, pẹlu Jeturi, ati Nefiṣi ati Nadabu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì bá àwọn ọmọ Hágárì jagun, pẹ̀lú Jétúrì, àti Néfísì àti Nádábù.