1 Chronicles 5:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀yà Juda di ẹ̀yà tí ó lágbára ju gbogbo ẹ̀yà yòókù lọ, tí wọ́n sì ń jọba lórí wọn, sibẹsibẹ ipò àkọ́bí jẹ́ ti àwọn ọmọ Josẹfu).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Juda bori awọn arakunrin rẹ̀, ati lọdọ rẹ̀ ni alaṣẹ ti jade wá; ṣugbọn ogún ibi jẹ ti Josefu:)
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí Júdà borí àwọn arákùnrin Rẹ̀, àti lọ́dọ̀ Rẹ̀ ni alásẹ ti ń jáde wá; ṣùgbọ́n ogún ìbí jẹ́ ti Jóṣẹ́fù),