1 Chronicles 5:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn ẹ̀yà náà ṣẹ Ọlọrun baba wọn, wọ́n pada lẹ́yìn rẹ̀, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bọ àwọn oriṣa tí àwọn tí Ọlọrun parun nítorí wọn ń bọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si ṣẹ̀ si Ọlọrun awọn baba wọn, nwọn si ṣe àgbere tọ awọn ọlọrun enia ilẹ na lẹhin, ti Ọlọrun ti parun ni iwaju wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì ṣẹ̀ sí Ọlọ́run àwọn baba wọn, wọ́n sì se àgbérè tọ àwọn ọlọ́run ènìyàn ilẹ̀ náà lẹ́yìn, tí Ọlọ́run ti parun ní iwájú wọn.