1 Chronicles 5:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Baali bí Beera, tí Tigilati Pileseri ọba Asiria mú lẹ́rú lọ; Beera yìí jẹ́ olórí ninu ẹ̀yà Reubẹni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Beera ọmọ rẹ̀, ti Tiglat-pilneseri ọba Assiria kò ni ìgbekun lọ; ijoye awọn ọmọ Rubeni ni iṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Béérà ọmọ Rẹ̀, tí Tígílátì-pílínésérì ọba Ásíríà kó ní ìgbékùn lọ: ìjòyè àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ni òun jẹ́.