1 Chronicles 5:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn arakunrin rẹ̀ ní ìdílé wọn, nígbà tí a kọ àkọsílẹ̀, ìran wọn nìyí: olórí wọn ni Jeieli, ati Sakaraya, ati
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn arakunrin rẹ̀ nipa idile wọn, nigbati a nkà itàn-idile iran wọn, Jeieli, ati Sekariah ni olori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn arákùnrin Rẹ̀ nípa ìdílé wọn, nígbà tí a ń ka ìtàn ìdílé ìran wọn: Jélíélì àti Ṣékáríà ni olórí.