1 Chronicles 6:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Merari ni: Mahili ati Muṣi. Àwọn ni baba ńlá àwọn ọmọ Lefi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Merari; Mahli ati Muṣi. Wọnyi si ni idile awọn ọmọ Lefi, gẹgẹ bi awọn baba wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Mérárì: Máhílì àti Múṣì. Wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ará Léfì tí a kọ ní ṣíṣẹ̀ ń tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí baba wọn: