1 Chronicles 6:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n ṣẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Geriṣoni nìwọ̀nyí: Libini ni baba Jahati, Jahati bí Sima,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti Gerṣomu; Libni ọmọ rẹ̀, Jahati ọmọ rẹ̀, Simma ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ti Gérísómù: Líbínì ọmọkùnrin Rẹ̀, Jéhátì Ọmọkùnrin Rẹ̀, Ṣímà ọmọkùnrin Rẹ̀,