1 Chronicles 6:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi fi àwọn wọnyi ṣe alákòóso ẹgbẹ́ akọrin ninu ilé OLUWA lẹ́yìn tí wọn ti gbé Àpótí Majẹmu OLUWA sibẹ;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi si ni awọn ti Dafidi yàn ṣe olori iṣẹ orin ni ile Oluwa, lẹhin igbati apoti-ẹ̀ri Oluwa ti ni isimi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ní àwọn ọkùnrin Dáfídì tí a fi sí ìdí orin nínú ilé OLÚWA lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sínmìn níbẹ̀.