1 Chronicles 6:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n ṣiṣẹ́ náà, pẹlu àwọn ọmọ wọn nìwọ̀nyí: Ninu ìdílé Kohati: Hemani, akọrin, ọmọ Joẹli, ọmọ Samuẹli,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi si li awọn ti o duro pẹlu awọn ọmọ wọn. Ninu awọn ọmọ Kohati: Hemani akọrin, ọmọ Joeli, ọmọ Samueli,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ó sìn pẹ̀lú ọmọ wọn: Láti ọ̀dọ̀ àwọn ará Kóhátítè: Hémánì olùkọrin, ọmọ Jóẹ́lì, ọmọ Ṣámúẹ́lì,