1 Chronicles 6:44 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Etani arakunrin wọn láti inú ìdílé Merari ni olórí àwọn ẹgbẹ́ akọrin tí ń dúró ní apá òsì rẹ̀. Ìran Etani títí lọ kan Lefi nìyí: ọmọ Kiṣi ni Etani, ọmọ Abidi, ọmọ Maluki;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn arakunrin wọn, awọn ọmọ Merari duro lọwọ osi: Etani ọmọ Kiṣi, ọmọ Abdi, ọmọ Malluku,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará Mérárì wà ní ọwọ́ òsì Rẹ̀: Étanì ọmọ Kísì, ọmọ Ábídì, ọmọ Málúkì,