1 Chronicles 6:74 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ilẹ̀ ẹ̀yà Aṣeri, wọ́n fún wọn ní Maṣali ati Abidoni;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati lati inu ẹ̀ya Aṣeri; Maṣali pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Abdoni pẹlu ìgberiko rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ẹ̀yà Áṣérì wọ́n gba Máṣálì Ábídónì,