1 Chronicles 6:75 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Hukoku ati Rehobu, pẹlu àwọn pápá oko àyíká wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Hakoku pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Rehobu pẹlu ìgberiko rẹ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Húkokì àti Réhóbù lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn;