1 Chronicles 6:79 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kedemotu ati Mefaati pẹlu àwọn pápá oko àyíká wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Kedemoti pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Mefaati pẹlu ìgberiko rẹ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kédémótì àti Méfátù, lápapọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko, tútù wọn;