1 Chronicles 6:80 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lára ilẹ̀ ẹ̀yà Gadi, wọ́n fún wọn ní Ramoti ní ilẹ̀ Gileadi ati Mahanaimu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati lati inu ẹ̀ya Gadi, Ramoti ni Gileadi pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Mahanaimu pẹlu ìgberiko rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Gádì wọ́n gba Rámóà ní Gílíádì Máhánáímù,