1 Chronicles 6:81 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Heṣiboni ati Jaseri, pẹlu àwọn pápá oko àyíká wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Heṣboni pẹlu ìgberiko rẹ̀, ati Jaseri pẹlu ìgberiko rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Hésíbónì àti Jáṣérì lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ pápá oko tútù wọn.