1 Chronicles 7:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn mẹrin ni ọmọ Isakari: Tola, Pua, Jaṣubu ati Ṣimironi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AWỌN ọmọ Issakari si ni, Tola, ati Pua, Jaṣubu, ati Ṣimroni, mẹrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísákárì: Tólà, Púà, Jáṣúbù àti Ṣímírónì, Mẹ́rin ni gbogbo Rẹ̀.