1 Chronicles 7:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Orúkọ àwọn ọmọ ati arọmọdọmọ Efuraimu yòókù ni Refa, baba Reṣefu, baba Tela, baba Tahani;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Refa si ni ọmọ rẹ̀ ọkunrin, Reṣefu pẹlu, ati Tela ọmọ rẹ̀, ati Tahani ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Réfà jẹ́ ọmọ Rẹ̀, Rẹ́sẹ́fì ọmọ Rẹ̀, Télà ọmọ Rẹ̀, Táhánì ọmọ Rẹ̀,