1 Chronicles 7:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Usi ni ó bí Isiraya. Isiraya sì bí ọmọ mẹrin: Mikaeli, Ọbadaya, Joẹli, ati Iṣaya; wọ́n di marun-un, àwọn maraarun ni wọ́n sì jẹ́ ìjòyè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Ussi: Israhiah ati awọn ọmọ Israhiah; Mikaeli, ati Obadiah, ati Joeli, ati Iṣiah, marun: gbogbo wọn li olori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ, Húṣì: Ísíráhíà. Àwọn ọmọ Ísíráhíà: Míkáélì Ọbádáyà, Jóẹ́lì àti Ísíhíáhì. Gbogbo àwọn máràrùn sì jẹ́ olóyè.