1 Chronicles 7:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Aṣeri nìwọ̀nyí: Imina, Iṣifa, Iṣifi ati Beraya, ati ọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Sera.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Aṣeri: Imna, ati Iṣua, ati Iṣuai, ati Beria, ati Sera, arabinrin wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ásérì: Ímíná, Ísúa, Ísúáì àti Béríá. Arábìnrin wọn sì jẹ́ Ṣérà.