1 Chronicles 7:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jafileti bí ọmọ mẹta: Pasaki, Bimihali, ati Aṣifatu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Jafleti: Pasaki, ati Bimhali, ati Aṣfati. Wọnyi li awọn omọ Jafleti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Jáfílétì: Pásákì, Bímíhátì àti Ásífátì. Wọ̀n yí ni àwọn ọmọ Jáfílétì.