1 Chronicles 7:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àkọsílẹ̀ ìran wọn ní ìdílé, àwọn baálé baálé ní ilé baba wọn, tí wọ́n jẹ́ akọni jagunjagun, gbogbo wọn jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ati igba (20,200).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati iye wọn, ni idile wọn nipa iran wọn, awọn olori ile baba wọn, akọni alagbara enia, jẹ ẹgbawa o le igba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìtàn ìdílé wọn láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn tí a kọ lẹ́sẹsẹ jẹ́ ti àwọn olórí ìdílé àti ẹgbẹ̀rún-ní ọ̀nà ogún-ó-lé nígba (20,200) Ọkùnrin alágbára