1 Chronicles 8:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Beraya ati Ṣema ni olórí àwọn ìdílé tí wọn ń gbé ìlú Aijaloni, àwọn sì ni wọ́n lé àwọn tí wọn ń gbé ìlú Gati tẹ́lẹ̀ kúrò;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Beria pẹlu, ati Ṣema, ti nwọn iṣe olori awọn baba awọn ara Ajaloni, awọn ti o le awọn ara Gati kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú Béríà àti Ṣémà, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Áíjálónì àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gátì kúrò.