1 Chronicles 8:38 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Aseli bí ọmọkunrin mẹfa: Asirikamu, Bokeru, Iṣimaeli, Ṣearaya, Ọbadaya, ati Hanani. Aseli ni baba gbogbo wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aseli si ni ọmọkunrin mẹfa, orukọ wọn ni wọnyi, Asrikamu, Bokeru, ati Iṣmaeli, ati Seraiah, ati Obadiah, ati Hanani. Gbogbo awọn wọnyi li ọmọ Aseli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áṣélì ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: Áṣíríkámù, Bókérù, Íṣímáélì, Ṣéáríà, Ọbádáyà àti Hánánì. Gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Áṣélì.