1 Chronicles 8:39 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Eṣeki, arakunrin Aseli, bí ọmọ mẹta: Ulamu ni àkọ́bí rẹ̀, lẹ́yìn náà Jeuṣi, lẹ́yìn náà Elifeleti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Eṣeki arakunrin rẹ̀ si ni Ulamu akọbi rẹ̀, Jehuṣi ekeji, ati Elifeleti ẹkẹta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ arákùnrin Rẹ̀ Éṣékì: Úlámù àkọ́bí Rẹ̀, Jéúṣì ọmọkùnrin ẹ̀ẹ̀kejì àti Élífélétì ẹ̀ẹ̀kẹ́ta.