bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare 1 Chronicles 9:30
1 Chronicles 9:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ alufaa yòókù ni wọ́n ń po turari,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati omiran ninu awọn ọmọ awọn alufa si fi turari ṣe ororo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú àwọn àlùfáà ni ó ń bojútó pípo tùràrí olóòórùn dídùn papọ̀.