1 Chronicles 9:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mikilotu bí Ṣimea; àwọn náà ń gbé lọ́dọ̀ àwọn eniyan wọn ni òdìkejì ibùgbé àwọn arakunrin wọn ní Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mikloti si bi Ṣimeamu. Awọn wọnyi si mba awọn arakunrin wọn gbe ni Jerusalemu, kọju si awọn arakunrin wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Míkílótì jẹ́ baba Ṣíméámì, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jérúsálẹ́mù.