1 Chronicles 9:44 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aseli bí ọmọkunrin mẹfa: Asirikamu, Bokeru, ati Iṣimaeli, Ṣearaya, Ọbadaya, ati Hanani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aseli si bi ọmọ mẹfa, orukọ wọn ni wọnyi; Asrikamu, Bokeru, ati Iṣmaeli, ati Ṣeariah, ati Obadiah ati Hanani. Wọnyi li awọn ọmọ Aseli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áṣélì ní ọmọ mẹ́fà, pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: Áṣíríkámù, Bókérù, Ísímáélì Ṣéáríà, Óbádíà àti Hánánì Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Áṣélì.