1 Chronicles 9:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Ṣilo ni Asaaya, àkọ́bí rẹ̀, ati àwọn ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ara Ṣilo, Asaiah akọbi, ati awọn ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tí ará Ṣílò: Ásáíà àkọ́bí àti àwọn ọmọ Rẹ̀.
Recommended Reading