1 Chronicles 9:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n wá láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini ni: Salu, ọmọ Meṣulamu, ọmọ Hodafaya, ọmọ Hasenua,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ Benjamini; Sallu, ọmọ Meṣullamu, ọmọ Hodafiah, ọmọ Senua.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níti ará: Ṣálù ọmọ Mésúlámì, ọmọ Hódáfíà; ọmọ Hásénúà;