1 Corinthians 1:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí ẹnikẹ́ni má baà wí pé orúkọ mi ni wọ́n fi ṣe ìrìbọmi fún òun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ẹnikẹni ki o máṣe wipe mo ti mbaptisi li orukọ emi tikarami.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà kò sí ẹni tí ó lè sọ pé òun ṣe ìtẹ̀bọmi ní orúkọ èmi fúnraara mi.