1 Corinthians 1:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nípa iṣẹ́ Ọlọrun, ẹ̀yin wà ní ìṣọ̀kan pẹlu Kristi Jesu. Òun ni Ọlọrun fi ṣe ọgbọ́n wa ati òdodo wa. Òun ni ó sọ wá di mímọ́, tí ó dá wa nídè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nipasẹ rẹ̀ li ẹnyin wà ninu Kristi Jesu, ẹniti Ọlọrun fi ṣe ọgbọ́n, ati ododo, ati isọdimimọ́, ati idande fun wa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí rẹ̀ ni ẹ̀yin ṣe wà nínú Kírísítì Jésù ẹni ti ó já sí ọgbọ́n fún wa láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run—èyi ń ni, òdodo, ìwà mímọ́ àti ìràpadà wa.