1 Corinthians 10:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo wọn ni wọ́n ṣe ìrìbọmi ninu ìkùukùu ati ninu òkun, kí wọ́n lè di ọmọ ẹ̀yìn Mose.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti a si baptisi gbogbo wọn si Mose ninu awọsanma ati ninu okun;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A lè pe eléyìí ní ìtèbọmi sí Mósè nínú ìkùúkù àti nínú omi òkun.