1 Corinthians 10:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí Oluwa ni ó ni ayé ati gbogbo nǹkan tí ó wà ninu rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe ti Oluwa ni ilẹ ati ẹkún rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí “Ayé àti gbogbo nǹkan rere tí ń bẹ nínú rẹ̀, tí Olúwa ni wọ́n jẹ́.”