1 Corinthians 10:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo wọn ni wọ́n jẹ oúnjẹ ẹ̀mí kan náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti gbogbo wọn si ti jẹ onjẹ ẹmí kanna;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípa iṣẹ́ ìyanu, gbogbo wọn jẹ oúnjẹ ẹ̀mí kan náà.