1 Corinthians 10:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ má ṣe jẹ́ ohun ìkọsẹ̀ fún àwọn Juu tabi fún àwọn tí kì í ṣe Juu tabi fún ìjọ Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ máṣe jẹ́ ohun ikọsẹ, iba ṣe fun awọn Ju, tabi fun awọn Hellene, tabi fun ijọ Ọlọrun:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, má ṣe jẹ́ òkúta ìkọ̀sẹ̀ (tí ó lè gbé ẹlòmíràn subú) ìbá à ṣe Júù tàbí Gíríkì tàbí ìjọ Ọlọ́run rẹ̀.