1 Corinthians 10:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn nǹkan wọnyi jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa, pé kí á má ṣe kó nǹkan burúkú lé ọkàn, gẹ́gẹ́ bí àwọn ti kó o lé ọkàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nkan wọnyi si jasi apẹrẹ fun awa, ki awa ki o má bã ṣe ifẹkufẹ ohun buburu, gẹgẹ bi awọn pẹlu ti ṣe ifẹkufẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀kọ́ tí a lè kọ́ yìí jásí àpẹrẹ fún wa, kí a má ṣe ní ìfẹ̀ sí àwọn ohun búburú gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn nínú ihà.