1 Corinthians 11:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo yìn yín nítorí pé ẹ̀ ń ranti mi nígbà gbogbo, ati pé ẹ kò jẹ́ kí àwọn ẹ̀kọ́ tí mo fi kọ yín látijọ́ bọ́ lọ́wọ́ yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ, ará, mo yìn nyin ti ẹnyin nranti mi ninu ohun gbogbo, ti ẹnyin ti di ẹ̀kọ́ wọnni mu ṣinṣin, ani gẹgẹ bi mo ti fi wọn le nyin lọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmí yìn yín fún rírántí mi nínú ohun gbogbo àti fún didi gbogbo ẹ̀kọ́ tí mo kọ́ ọ yín mú sinsin gẹ́gẹ́ bí mo ṣe fi lélẹ̀ fún un yín.