1 Corinthians 12:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí kì í ṣe ẹ̀yà kan ṣoṣo ni ara ní; wọ́n pọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe ara kì iṣe ẹ̀ya kan, bikoṣe pupọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni, ara, kì í ṣe ẹ̀yà kan ṣoṣo bí kò ṣe púpọ̀.