1 Corinthians 12:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ó bá jẹ́ pé ẹ̀yà kan ṣoṣo ni gbogbo ara ní, níbo ni ara ìbá wà?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi gbogbo wọn ba si jẹ ẹ̀ya kan, nibo li ara iba gbé wà?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí gbogbo wọn bá sì jẹ́ ìkanṣoṣo nínú ẹ̀yà-ara, níbo ni ara yóò gbé wà.