1 Corinthians 12:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ó ti wà yìí, ẹ̀yà pupọ ni ó ní, ṣugbọn ara kan ṣoṣo ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nisisiyi, nwọn jẹ ẹya pupọ, ṣugbọn ara kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run dá ẹ̀yà ara púpọ̀, ṣùgbọ́n ara kan ṣoṣo ni.