1 Corinthians 12:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Oríṣìíríṣìí ni ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ ṣugbọn láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí kan náà ni wọ́n ti ń wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ onirũru ẹ̀bun li o wà, ṣugbọn Ẹmí kanna ni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ onírúurú ẹ̀bùn ni ó wà, ùgbọ́n Ẹ̀mí kan náà ni.