1 Corinthians 12:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Iṣẹ́ Ẹ̀mí Mímọ́ ń farahàn ninu olukuluku wa fún ire gbogbo wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn a nfi ifihàn Ẹmí fun olukuluku enia lati fi jère.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n à ń fi ẹ̀bùn Ẹ̀mí fún olúkúlùkù ènìyàn láti fi jèrè.