1 Corinthians 14:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn bí ẹnikẹ́ni kò bá gba ohun tí a wí yìí, a kò gba òun náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi ẹnikan ba jẹ òpe, ẹ jẹ ki o jẹ òpe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n bí ẹnikan bá fi ojú fo èyí dá, òun fún ra rẹ̀ ní a ó fi ojú fò dá.