1 Corinthians 15:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tí ó bá wá rí bẹ́ẹ̀, a jẹ́ pé àwọn onigbagbọ tí wọ́n ti kú ti ṣègbé!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ awọn pẹlu ti o sùn ninu Kristi ṣegbé.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ àwọn pẹ̀lú tí ó sùn nínú Kírísítì ṣègbé.