1 Corinthians 15:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fara han Peteru. Lẹ́yìn náà ó tún fara han àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati pe o farahan Kefa, lẹhin eyini awọn mejila:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti pé ó farahàn Pétérù, lẹ́yìn èyí, àwọn méjìlá