1 Corinthians 15:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ó fara han Jakọbu, ó sì tún fara han gbogbo àwọn aposteli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lẹhin eyini o farahan Jakọbu; lẹhinna fun gbogbo awọn Aposteli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn èyí ni ó farahan Jèmísì; lẹ́yìn náà fún gbogbo àwọn Àpósítélì.