1 Corinthians 16:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Masedonia ni n óo kọ́ gbà kọjá, n óo wá wá sọ́dọ̀ yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o tọ̀ nyin wá, nigbati emi ba ti kọja lọ larin Makedonia: nitori emi ó kọja larin Makedonia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n èmi yóò tọ̀ yin wá, nígbà tí èmí bá ti kọjá láàrin Makedóníà: nítorí èmi yóò kọjá láàrin Makedóníà.