1 Corinthians 2:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Ta ni ó mọ inú Oluwa? Ta ni yóo kọ́ Oluwa lẹ́kọ̀ọ́?” Ṣugbọn irú ẹ̀mí tí Kristi ní ni àwa náà ní.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe tali o mọ̀ inu Oluwa, ti yio fi mã kọ́ ọ? Ṣugbọn awa ni inu Kristi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí ta ni ó mọ ọkàn Olúwa, ti yóò fi máa kọ́ Ọ?” Ṣùgbọ́n àwa ní inú Kírísítì.